Smiley face

Olówó ń sọrẹ olówó: Ọmọ Otedola pàdé Dangote

Ni orileede India, nibe ni Otedola, oyinbo elepo robi, tí gbé pade Alh Aliko Dangote. Ibe náà ni DJ Cuppy to jẹ ọmọ Otedola tí gbé yọmọ Dangote tí àwọn méjèèjì sì jọ yà foto papọ.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment