Smiley face

"Ìdí tí oṣù kejì ọdún fi ṣe pàtàkì sì mi" - Olajumoke ọmọ oniburedi

"Oṣù kejì ọdún je àkókò ìyanu àti àgbàrá Ọlọ́run láyé mi. Nínú oṣù yìí ni ori gbemi pade TY Bello to fi Camera 📸 rẹ gbà osuka lórí mi.

Inú oṣù náà ni igbe ayé mí yí padà, ti mo sì di olókìkí ńlá. Inú oṣù kejì náà ni ọjọ ìbí mi. Mo dúpẹ́ fún ààbò àti idasi Ọlọ́run. Ẹ bá mi yọ, ajọyọ ọjọ́ ìbí mi wọlé de. " Olajumoke Orisaguna

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment