Smiley face

Aisha Buhari níbi ìgbéyàwó àwọn ọmọ gómìnà nílùú Ìbàdàn

Aisha Buhari aya Ààrẹ Muhammadu Buhari náà wá síbi ayẹyẹ ìgbéyàwó àwọn ọmọ gómìnà ipínlẹ̀ Ọ̀yọ́ àti gomina ìpínlè Kano eléyìí to wáyé lópin ọsẹ yii nílùú Ìbàdàn.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment