Smiley face

Ayẹyẹ Ìgbéyàwó àti òjò ibi Wasiu Ayinde Marshal fakíki

Lọjọ Satide to kọjá, 03/03 /2018, bí Abolaji Ajimobi àti aya rẹ, Fateema Ganduje, tí àwọn wọn méjèèjì jẹ ọmọ gómìnà ipínlẹ̀ Ọ̀yọ́ àti gomina ìpínlè Kano ṣe ń so yigi wọn bẹẹ naa ni Ọba Fuji, K1, náà so yigi ololufe rẹ, Opeyemi Adufe Fatia.

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wí pé àwọn méjèèjì tí ń fẹ́ ara wọn ti pe, ṣùgbọ́n ọba Fuji pinnu láti sọ yigi arábìnrin náà lábẹ́ òfin lọjọ kan náà tí ń yọ ayọ̀ ọjọ́ ìbí ọdún kokanlelọgota (61). Àríyá yìí ló wáyé láàfin Ọba Fuji, ilé funfun alagbala ńlá tó kalẹ sì Ìjẹ̀bú òde, Ojushagbola’s Castle. Lára ohun to tún ṣẹlẹ̀ nibe ni bí oga oniroyin onirawo méje lápá, Femi Davies, tún fi àmì ẹyẹ dá Olú Ọmọ tiluu Èkó lola gẹ́gẹ́ bí akọni olórin ilé Adúláwò pátá.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment