Smiley face

Ènìyàn bí Rev. Mother Esther Abimbola Ajayi

Rev. Mother Esther Abimbola Ajayi, adari ijo Love Of Christ Generation C&S to wá ni Clapham nílùú  London ni ènìyàn pàtàkì wa fún ọsẹ yii. 

Kárí ayé ni wọn ti ń sọ̀rọ̀ ìyá yìí gege bí onínú irẹ àti ojisẹ Ọlọ́run tòótọ́. Ìyá yìí je ẹlẹmi ìrèlẹ̀ gbogbo ènìyàn patata lọ sí ń bá ṣe. 

A gbàdúrà wí pé Ọlọ́run yóò tún má fún ní ọrẹ ọ̀fẹ́ láti tesiwaju. Àmìn 

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment