Smiley face

Happy Birthday Prof: Ènìyàn bí Yemi Osinbajo wón bí oju

E má jẹ ki n parọ fún yín. Lára ona kan pàtàkì lati se àkíyèsí bóyá ènìyàn jẹ ọlọ́gbọ́n tàbí bẹẹkọ ni nípa fi fún ẹni bẹẹ láàyè láti sọ ọrọ ẹnu rẹ jade. Ìrírí mi sì fi yẹ wí pé ènìyàn lágbára láti fẹjẹ sínú kí wọn sì ma tutọ fún jáde. Yemi Elebuibon lọ so wí pé "èèyàn wón," ṣùgbọ́n mo d'Oshodi èrò yapa. Ènìyàn burúkú lọ pọ̀ bí erùpẹ̀, àwọn ènìyàn rere sí wọn bí ojú.

Mo fi àsìkò yìí kì Ọ̀jọ̀gbọ́n Yemi Osinbajo, igbakeji Aare ilẹ̀ Nàìjíríà, kú ọjọ́ ìbí ọdún kokanlelogota (61)

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment