Smiley face

"Boko Haram pa ènìyàn méjìlá, wọn tún padà wá pa mẹẹdogun níbi wọn ti ń sìnkú àwọn méjìlá akoko"- BBC Hausa

Ileese ìròyìn BBC, ẹ ka tí èdè Hausa tí kéde bí àwọn Boko Haram ṣe pa ènìyàn méjìlá ni Zamfara. Bákan náà ni wọn tún padà wá lọ́jọ́ kejì níbi wọn ti ń sìnkú àwọn ènìyàn méjìlá àkọ́kọ́ tí wọn sì tún wá pa mẹẹdogun ní ìpínlè Zamfara.

"Gunmen killed 12 people in a village in Zamfara yesterday, returned to same village today and 15 during the burial of the initial 12"

- BBC Hausa

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment