Smiley face

Kò sí ohun tí mi lé ṣe láti bá Olamide Baddo sun - Ọmọge Olosho

Àwọn asewo àsìkò yìí kò tile lójútì mọ. Ọmọbìnrin kan lọ ní kó sì ohun tí òun kò lè ṣe láti rí dájú wí pé òun bá Olamide Adedeji tí gbogbo ènìyàn mo sì Baddo sun.

Ọmọbìnrin náà láyè gelete, ẹyin rẹ náà kò sì bajẹ. Ó dájú wí pé ìṣe burúkú lọmọ náà ni lati jẹ́.

Ṣùgbọ́n sá, kí ló ń wá Olamide fún nígbà tí Tboy wá lOshodi, tí ẹ bá dé Agege ẹ béèrè Konga. Àwọn tí mo ń sọ yii leru lábẹ́ fa. Ènìyàn mi lOga Ńlá Ketu, àwọn eléyìí lè fi kùmọ̀ fólé.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment