Smiley face

O ti jasire: Bukola Oni tí diyàwó tuntun

Mi ò lọrẹ to pò, díẹ ni àwọn ọrẹ mi; lára wọn sì ni Bukky wá.

Bukky a má lo inú kan, ó nifẹ àwọn ènìyàn, bákan ló jẹ́ akíkanjú obìnrin.

Mo gbàdúrà ọmọ ìdùnnú, owó tabua, ayọ̀ alai lodinwọn, àlàáfíà àti èmi gigùn fún ìdílé rẹ.

Àmìn #HML

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment