Smiley face

Wọn tí dá eérú sójú sójà mokanla - Akoni ni gbogbo wọn

Tí ẹ bá wà nílè tẹ ẹ ń jẹyan oko, tàbí ẹ wá lóde àríyá níbi ti fàájì tí gbé dùn yungbayungba; ẹ má gbegbe wí pé àwọn kan wà l'Òkè Oya tí wọn fara gbọta Boko Haram kí awa lè wá nidẹra.

Mokanla tí wọlẹ̀ sún nínú wọn lọnii. Ẹ má gbàgbé wọn. 🙏 😔 😢

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment