Smiley face

Adigunjale wọ Offa, wọn kówó, wọn tún fẹ̀mí ṣòfò

Àwọn adigunjale wọ ilu Offa lọjọ karùn-ún oṣù kẹrin ọdún yìí láti fọ banki. Àìmọye èmi lo ṣòfò, lára wọn ni ọlọ́pàá àti àwọn obìnrin.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

1 comments:

  1. Ki Olorun jowo bawa segun itaje sile ni nigeria.... Amin

    ReplyDelete