Smiley face

Báyìí ni Ààrẹ Buhari ṣe yẹ̀yẹ́ àwọn ọ̀dọ́ Nàìjíríà ni ilu London

"Nnkan ọ̀fẹ́ tí baye àwọn ọ̀dọ́ Nàìjíríà jẹ. Wọn kò fẹ ohunkóhun ṣe, gbogbo ìgbà, sáà-ba-n-mu lorin tí wọn kọ. Bí sádákà, bí ìfà ni wọn má ń retí ni gbogbo ọjọ́ ayé wọn" - Ààrẹ Buhari dọti àwọn ọ̀dọ́ Nigeria lójú àwọn òyìnbó nílùú London

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment