Smiley face

Gómìnà ipínlẹ̀ Kano fi ori ru iyẹ̀pẹ̀ lónìí

Ẹnu yà ọ̀pọ̀lọpọ̀ lónìí nígbà tí gómìnà ipínlẹ̀ Kano, Abdullahi Ganduje, ṣe abewo si ise àkànṣe kan tí ń lọ lọ́wọ́.

Gómìnà rí àwọn ènìyàn tí ń ṣíṣẹ lọ bá wí pé, "Ẹ fún mi ni sọbiri". Baba bá bẹ̀rẹ̀ si ni bù yanrin sínú pọnpọn.

Igba to ṣe báyìí tán lọ bá tún wí pé, ẹ gbé ru mi, a ni ẹ gbe ru mi". Ẹnu yà gbó àwọn ènìyàn wọn sì bẹ̀rẹ̀ si ni kan saara sì gómìnà náà gege bí asiwaju gidi.

Jugbogbo rẹ lọ, àwọn onwoye nípa òṣèlú so wí pé, nǹkan bí oṣù bí mẹ́wàá lo kù ki eto ìdìbò míì  wọlé de. Akojopo ìrírí wọn sì fìdí rẹ múlè wí pé, pupọ àwọn gómìnà tí wọn ba parí sáà àkọ́kọ́ ma ń fẹ́ gbìyànjú eleekeji. Se akitiyan Ganduje dá lórí sáà kejì àbí bẹẹkọ?

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment