Smiley face

Ìyàwó alarede gun ẹṣin funfun wọ sọọsi

Ni Tudun Wada to wá nílùú Jos, ìyàwó alarede gun ẹṣin funfun wọ sọọsi. Gbogbo àwọn ènìyàn ń juwọ sìi lọtún losi, bẹ́ẹ̀ ni òun náà bóyín sí wọn padà bí ẹni tó ṣẹ̀ṣẹ̀ gbowó NairaBet. 😂

Igba àkọ́kọ́ ni yìí ti ìyàwó tuntun yóò dá irú ara yìí ni àgbègbè náà, iṣẹlẹ náà sì mú òkìkí ìgbéyàwó náà tán kiri.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment