Smiley face

Ohun tí àwon olopaa ṣe fún ìyá àgbàlagbà ni Abia ni yii

Tí bá ń sọ nípa àwọn tí wọn wù ìwà ibajẹ, ó yẹ ká sọ nípa àwọn ọmọlúwàbí pẹ̀lú. Ní ìpínlè Abia, ìyá àgbàlagbà to ń bọ láti oko dá ẹyìn rẹ nù, àwọn olopaa ti won  kọjá lọ dúró láti rán an lọ́wọ́. Ẹ rí wí pé wọn ṣe dáadáa... 👏

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment