Smiley face

Oluwo tí ilu Iwo ti padà pelu ara tuntun

Oluwo tí Ìwọ, Oba Abdul Rasheed Akanbi tún gbéyo pelu ara tuntun nígbà tó dáṣẹ̀ jade láàfin rẹ pẹlu aṣọ onisokoto tiirin.

Tí ẹ kò bá gbàgbé, laipe yii ni Ọba yìí yìí orúkọ oyè rẹ sì Emir eléyìí to tí ń fà  àríyànjiyàn lórí ayélujára.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment