Smiley face

Ọmọbìnrin to bọ lọ́wọ́ cancer tí gbé ìgbà ọpẹ

"Ni iru àkókò yìí lodun tó kọjá, mo sebi ohun tó kàn fún mi ní ikú. Ṣùgbọ́n ikú kò wù mú kú. Ara ń ní mi, àìsàn jẹjẹrẹ kò jẹ ń gbádùn, mo kan rẹ́ rìn ín yangi lásán ni.

Ṣùgbọ́n nígbà tó yá, Ọba onisẹ ìyanu de. Ó gbà kádàrá ikú, ó sì fún mi ní ìyè. Ẹ bá mi dúpẹ́, ẹ bá mi sọ fún gbogbo ayé wí pé alágbára ni Ọlọ́run oga ògo". - Shannee Wilson

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment