Smiley face

Òpin àwọn ọmọ Yahoo-yahoo

Ilé táa fitọ́ mọ, ìrì lásán ni ó wo dànù. Joojumọ ni wọn sebi ọlọba. Wọn a náwó bí ẹni wí pé ilẹ̀ ọ̀la kò ní mọ́. Ọ̀pọ̀ tí ń ṣe bigimaanu lóde niṣe ọwọ wọn kò mọ. Òtítọ́ lọrọ Orlando Owoh. Àwọn ọmọ Yahoo-yahoo tí wọn gbé ní Lekki tí kò sọ́wọ́ EFCC báyìí.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment