Smiley face

Gani Adams náà tí kàwé gboyè ni LASU

Ààrẹ Ọ̀nà Kakanfo Ilẹ̀ Yorùbá, Iba Gani Abiodun Ige Adams náà tí padà kàwé gboyè ni ile ẹ̀kọ́ Yunifásítì. Ṣebi àwọn Yorùbá lóní imọ kò pín síbì kan. Àwọn aláṣẹ ọgbà LASU ni ohun ìyangàn ńlá lọ je fún àwọn láti gba olórí ẹgbẹ́ OPC àti OPU àgbáyé sínú ọgbà wọn gẹ́gẹ́ bí akẹ́kọ̀ọ́. 

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment