ORÚKỌ ÀWỌN ALÁÀFIN Ọ̀YỌ́ TO TÍ JẸ ṢÁÁJÚ KÒ TO WA KAN ALÁÀFIN ÀSÌKÒ YÌÍ 1 - Oranmiyan 2 - Ajaka 3 - Shango 4 - Aganju 5 - Kori 6 - Olu...
Read More
Home / Isese Yoruba
Showing posts with label Isese Yoruba. Show all posts
Showing posts with label Isese Yoruba. Show all posts
Lára ohun tó mú Yorùbá yàtò gedegbe ni yìí
Yorùbá kìí rìn ìrìn ìdọ̀tí. Yorùbá kìí wọ akisa. Yorùbá lónìí ká wọ buba, ká wọ ṣòkòtò, ká wá gbé agbádá le e lórí. Yorùbá lo ní ká rí ẹni,...
Read More
Oluwo tí ilu Iwo ti padà pelu ara tuntun
Oluwo tí Ìwọ , Oba Abdul Rasheed Akanbi tún gbéyo pelu ara tuntun nígbà tó dáṣẹ̀ jade láàfin rẹ pẹlu aṣọ onisokoto tiirin. Tí ẹ kò bá gbàgb...
Read More
Yorùbá Ni Tòótọ́: Yorùbá kò ní pẹ tán tí a kò bá mọ nípa ìtàn wa
Mensa Otabil, olùkọ́ni , onkọ̀wé , olokoowo ńlá, àti ẹni àkọ́kọ́ ti yóò ṣe idasilẹ Yunifásítì aladani ni orileede Ghana sọ wí pé, "àwọn...
Read More
Lọ́jọ́ tí wọn fi Femi Branch jẹ Jagun Asa
Won ni bí a kò ba rí ẹyẹ igun a gbọ́dọ̀ ṣebọ, bí a kò rí ẹyẹ akala a gbọdọ sorò, bí a kò bá ti rí ewé akòko kò sí bá a ti fẹ́ joyè nílẹ̀ yìí...
Read More
Subscribe to:
Comments
(
Atom
)