Muzzamil Umar Muzzamil Umar jo gbogbo aye loju nigba to fun ara se moto ni ipinle Kebbi. Omo odun mokanlelogun (21), eni to wa ni SS3 ...
Read More
Home / Yoruba
Showing posts with label Yoruba. Show all posts
Showing posts with label Yoruba. Show all posts
"Sukura, akobi K1 loyun fagbero"- ALARIYA OODUA lo so bee
Lati inu iwe Iroyin Alariya Oodua ni iroyin yii ti jade wi pe, akobi omobirin Wasiu Ayinde ti gboyun lowo agbero onimoto kan ni agbegbe K...
Read More
“Ona ti a gba yanju Ebola ma yato si ti iba Lassa”- Ojogbon Adewole
Ojogbon Isaac Adewole Ijoba apapo labe akoso Aare Muhammadu Buhari tun ti fi awon ara ilu lokan bale nipa akitiyan won lati kase...
Read More
Buhari setan lati maa ja aadota (50) naira lori owo onibara banki
Aare Muhammadu Buhari Nibayii, ijoba apapo, labe akoso Muhammadu Buhari, ti pase wi pe, awon yoo ma ja aadota naira (N50) lori owo t...
Read More
Bill Gates towo bo iwe adehun pelu Dangote
Dangote ati Gates Bill Gates, eni ogota odun (60yr) to tun je okunrin to lowo ju lagbay e, ti wo ilu Naijiria lati towo bowe ade...
Read More
Subscribe to:
Comments
(
Atom
)