Aare Buhari ni ilu Ghana 🇬🇭 níbi ayẹyẹ ayajọ òmìnira ìlú náà.
Read More
Home / oselu
Showing posts with label oselu. Show all posts
Showing posts with label oselu. Show all posts
Sugar ja ni Kano níbi ìgbéyàwó ọmọ gómìnà ipínlẹ̀ Ọ̀yọ́ àti gomina ìpínlè Kano
Ọrùn wọ ipínlẹ̀ Kano lánàá, 3/03/2018, nígbà ti àwọn alágbára, alẹnulọrọ olóṣèlú ilẹ̀ Nàìjíríà sọkalẹ si ipínlẹ̀ náà pelu bàálù orísìírísìí ...
Read More

"Iro ni won pa mọ mi o, mi ò setan lati gbe àpótí idibo ààrẹ"- Fela Durotoye lọ sọ bẹẹ
Gbajugbaja, olukoni gbogbogbòò , onimo pàtàkì nípa ìṣàkóso àti ọ̀rọ̀ ìṣípayá, Ogbeni Fela Durotoye tí kede wí pé òun kò mọ nípa fọ́tò òun ti...
Read More
Bolaji Abdullahi fò mọ́ Lérè Olayinka lọ́rùn lójútaye : Bolaji ni iro ni Lérè ń pa.
Láàárín Lérè Olayinka, amugbalegbe fún eto ìròyìn ayelukara fún gómìnà Ayodele Fayose àti Akowe iponlongo fún ẹgbẹ́ APC àpapò. Ta ló ń parọ...
Read More

Atiku ti pada leyin Tinubu ati egbe APC
Atiku ti kede wi pe oun ti kuro ninu egbe APC. Bi o tile je wi pe ko ti so pato nipa egbe oselu to fe darapo mo. Sibesibe, igbagbo ati ahes...
Read More
Subscribe to:
Posts
(
Atom
)