Ninu idije ese kíkan tó wáyé ní ilẹ Biritiko lọjọ Satide to kẹyin oṣù kẹta, 31/03/2018, àná fò lójú ni Anthony Joshua na Joseph Parker
Read More
Home / All post
Saheed Osupa Ọba Orin ti de pelu Non Stop awo orin tuntun
King Saheed Osupa tí setan láti gbé àwo orin tuntun jáde eléyìí tí wọn pé ní Non Stop.
Read More
Asiwaju Oko Fàájì: K1 bàbà oloye tuntun
Wọn tí fi King Wasiu Ayinde Marshal jẹ Asiwaju Oko Fàájì lánàá, 31/03 /2018 ní ìlú Èkó. Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìròyìn mbo laipe
Read More
Bukola Saraki tí ṣe tán láti díje fún ipò ààrẹ ọdún 2019
Ààrẹ ilẹ̀ ìgbìmọ̀ asofin àgbà Abuja, Bukola Sàràkí tí fi ìfẹ́ rẹ̀ hàn láti díje ipò aare orileede Nàìjíríà lọ́dún 2019. Gẹ́gẹ́ bí Olóòtú ìw...
Read More
Arẹwà Olorì Oluwo tí ilu Iwo
Olorì Ọba Abdulrasheed Adewale Akanbi, Oluwo tí Iwo
Read More
Subscribe to:
Comments
(
Atom
)