Smiley face

Aṣọ Mercy Aigbe to dá wàhálà silẹ ni yìí

Àríyá... níbi ayẹyẹ ọjọ́ ìbí Kemi Afolabi. Àwọn ènìyàn sọ wí pé aṣọ ti Mercy Aigbe wọ kò dára tó nígbà ti àwọn kan rí gẹ́gẹ́ bí oge lásán el...
Read More

Odunlade Adekola yege: Irawo osere náà kàwé gboyè

Kò sí ìgbà táa dásọ tá rilẹ fiwọ́. Odunlade Adekola tí padà kàwé gboyè. Congratulations 🎊
Read More

ORÚKỌ ÀWỌN ALÁÀFIN Ọ̀YỌ́ TO TÍ JẸ ṢÁÁJÚ KÒ TO WA KAN ALÁÀFIN ÀSÌKÒ YÌÍ

ORÚKỌ ÀWỌN ALÁÀFIN Ọ̀YỌ́ TO TÍ JẸ ṢÁÁJÚ KÒ TO WA KAN ALÁÀFIN ÀSÌKÒ YÌÍ 1 - Oranmiyan 2 - Ajaka 3 - Shango 4 - Aganju 5 - Kori 6 - Olu...
Read More

Lára ohun tó mú Yorùbá yàtò gedegbe ni yìí

Yorùbá kìí rìn ìrìn ìdọ̀tí. Yorùbá kìí wọ akisa. Yorùbá lónìí ká wọ buba, ká wọ ṣòkòtò, ká wá gbé agbádá le e lórí. Yorùbá lo ní ká rí ẹni,...
Read More