Smiley face

Aṣọ Mercy Aigbe to dá wàhálà silẹ ni yìí

Àríyá... níbi ayẹyẹ ọjọ́ ìbí Kemi Afolabi. Àwọn ènìyàn sọ wí pé aṣọ ti Mercy Aigbe wọ kò dára tó nígbà ti àwọn kan rí gẹ́gẹ́ bí oge lásán eléyìí tí kò lábùkù kankan. Kini èrò tí yín?

Ohun tí àwon ènìyàn sọ wá NIBI:

https://www.facebook.com/groups/letakanako/permalink/1940651375986162/

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment