Smiley face

Ìrìn àjò wákàtí kan: Ọkọ̀ ojú irin Ibadan d'Eko ti fẹ́ parí - Kongila

Ìṣe ń lọ lọ́wọ́ báyìí nípa ìṣe ọna ojú-irin tí reluwe yóò má rìn láàárín ìlú Èkó sì ìlú Ìbàdàn. Àwọn agbase ṣe náà so wí pé, oṣù Kejìlá ọdún 2018 ni ise naa yoo parí. Wákàtí kan péré ni yóò sì ma gba àwọn ènìyàn láti rin irin àjò láàárín Ibadan sì ìlú Èkó.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment