Smiley face

Omowe Adesina fi geesi ko ede Yoruba pombele

Omowe Oluwole Adesina

Tiwa-n-tiwa takisa taatan. Omowe Wole Adesina ti se agbekale iwe eko ede Yoruba pelu ede geesi to pegede fun ojulowo eko ede Yoruba to kun fofo bi ataare. 

Akanse iwe yii ni Omowe Adesina se fun awon omo Odudua ti won bi si oke okun, paapa ju lo, awon ti won bi si orileede Amerika. 
Iwe yii kan naa wulo fun awon obi ti won ko mo nipa ede Yoruba eleyii ti yoo ran won lowo lati fi eko naa ko awon omo won. 

Ogbontarigi onise alakada yii se iwe yii lati se iranwo fun awon omo Yoruba ti won jina sile baba won. Eleyii to gba wi pe yoo wulo fun imo ede Yoruba gidi.

Awon Yoruba bo, won ni toko o ba jina, ila ki i ko. Iwe ti won pe akole re ni: YORUBA ALPHABET FOR LEARNERS IN THE UNITED STATES
ni e le rira NIBI.

http://www.lulu.com/shop/wole-adesina-phd/yoruba-alphabet-for-learners-in-the-united-states/paperback/product-20589222.html

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment