"Bukola Sàràkí ni bàbá ìsàlẹ̀ wa" Awọn adigunjale banki Ọfa tí jẹwọ Olayemi Oniroyin 6/03/2018 06:54:00 pm Add Comment Edit Ni olu ileesẹ ọlọ́pàá nílùú Abuja, wọn ti ṣe àfihàn àwọn afurasi adigunjale tí wọn ṣekú pa àìmọye nílùú Offa, Ìpínlẹ̀ Kwara. Àwọn afurasi a... Read More
Dangote kò àádọ́jọ (150) ọkọ̀ kalẹ fún àwon ọlọ́pàá Olayemi Oniroyin 5/31/2018 10:06:00 pm Add Comment Edit Dangote Foundation eléyìí to jẹ àjọ tí Alh Aliko Dangote gbé kalẹ láti lè fi má rán àwùjọ lọ́wọ́ tí pèsè àádọ́jọ (150) ọkọ fún ilé ìṣe ọlọ́p... Read More
"Bàbá mi má ń fẹnu fà ọyàn mi, bákan náà lo bá mi ni ajosepo fún ọdún mẹ́rin" Olayemi Oniroyin 5/25/2018 06:23:00 am Add Comment Edit "Bàbá mi má ń fẹnu fà ọyàn mi, bákan náà lo bá mi ni ajosepo fún ọdún mẹ́rin" Ọmọbìnrin ẹni ọdún méjìdínlógún (18) tí bàbá rẹ̀ n ... Read More
Gani Adams náà tí kàwé gboyè ni LASU Olayemi Oniroyin 5/24/2018 06:06:00 pm Add Comment Edit Ààrẹ Ọ̀nà Kakanfo Ilẹ̀ Yorùbá, Iba Gani Abiodun Ige Adams náà tí padà kàwé gboyè ni ile ẹ̀kọ́ Yunifásítì. Ṣebi àwọn Yorùbá lóní imọ kò pín s... Read More
Meji nínú àwọn olè Ofa tí de òpin ìrìn àjò wọn Olayemi Oniroyin 5/22/2018 10:17:00 am Add Comment Edit Ọwọ́ àwọn ọlọ́pàá Nàìjíríà tí tẹ àwọn méjì míì tí wọn wá lára àwọn adigunjale tí wọn ṣekú pa àìmọye ènìyàn l'Ofa. Ohun tí a gbọ ni wí p... Read More
Boko Haram gbiyanju lati fẹ̀mí ṣòfò nínú awẹ Ramadan Olayemi Oniroyin 5/21/2018 11:25:00 pm Add Comment Edit Àìmọye èmi ni Boko Haram kò bá rán lọ sọ́run lópin ọsẹ tó kọjá yìí, 20/05/2018, níbi wọn ti n gbìyànjú láti dáná bombu 💣 sì mọsa... Read More
Dangote tí bẹ̀rẹ̀ si ni ṣe moto Peugeot jáde báyìí Olayemi Oniroyin 5/21/2018 10:50:00 am Add Comment Edit Alhaji Aliko Dangote, ènìyàn dúdú to lowo ju lagbaye tí ṣetan báyìí láti má ṣe àwọn ọkọ pijó jáde ní ìlú Kaduna. Dangote Peugeot Automobile ... Read More
Àwọn ará ìlú ṣe ayẹyẹ ọjọ́ ìbí fún ọlọ́pàá "yellow fever" olótìítọ́ Olayemi Oniroyin 5/19/2018 01:44:00 pm Add Comment Edit Àsegbé kan kò sì láyé, àsepamọ́ ló wà. Ọkùnrin tí orúkọ n jẹ Ifedioranma Darlington tí ń sisẹ́ adari ọkọ̀ ojú pópónà ni ìkòríta Aroma nílùú... Read More
Báyìí ni Ìyá Dare onigbin ṣe pàdé gómìnà, kositọma rẹ àtijọ́ Olayemi Oniroyin 5/14/2018 09:42:00 am Add Comment Edit "Mo má ń sọ fún àwọn ènìyàn wí pé Kositọma mi àtijọ́ ni gomina ṣùgbọ́n wọn kì í gba mi gbọ - Ìyá Dare onigbin ni Owena. Ó ti pe tí Ìyá... Read More
Ìrìn àjò wákàtí kan: Ọkọ̀ ojú irin Ibadan d'Eko ti fẹ́ parí - Kongila Olayemi Oniroyin 5/10/2018 11:13:00 pm Add Comment Edit Ìṣe ń lọ lọ́wọ́ báyìí nípa ìṣe ọna ojú-irin tí reluwe yóò má rìn láàárín ìlú Èkó sì ìlú Ìbàdàn. Àwọn agbase ṣe náà so wí pé, oṣù Kejìlá ọdún... Read More
Wọn tí dá ọlọ́pàá to mú Evans àti Godogodo lóla nílùú Abuja Olayemi Oniroyin 5/10/2018 06:30:00 pm Add Comment Edit Wọn tí fi irawo kún irawo Abba Kyari nílùú Abuja. Ogbontarigi ọlọ́pàá ọlọtẹlẹmuyẹ to rẹyìn àwọn ògbólógbòó ọ̀daràn bí Godogodo, Evans ajini... Read More
Àwọn ọmọ ìbejì ọkùnrin ọmọ ọdún mẹta ti won ba ara wọn sún tí dá wàhálà silẹ l'Eko Olayemi Oniroyin 4/26/2018 07:26:00 pm Add Comment Edit Òpin ayé tí de o! Ẹ WA GBỌ OHUN TÓ ṢẸLẸ̀. Àwọn ọmọ ìbejì ọkùnrin, ọmọ ọdún mẹta, ni wọn ba ara wọn ní ajọsepọ ni àgbègbè Ajah to wá nílùú E... Read More
Orúkọ Abba Kyari tí di ibẹru fún àwọn ọ̀daràn Olayemi Oniroyin 4/23/2018 01:17:00 pm Add Comment Edit Akíkanjú ọlọ́pàá ọlọtẹlẹmuyẹ, Abba Kyari, to lè iwájú ikọ elenu márùn-ún lè logoji tí wọn sise láti rí wí pé owó tẹ Evans, ògbólógbòó ajinig... Read More
Omoyele Sòwòrẹ́ tí balẹ sì ipínlẹ̀ Edo Olayemi Oniroyin 4/21/2018 02:00:00 pm Add Comment Edit Read More
Òpin àwọn ọmọ Yahoo-yahoo Olayemi Oniroyin 4/12/2018 08:49:00 am Add Comment Edit Ilé táa fitọ́ mọ, ìrì lásán ni ó wo dànù. Joojumọ ni wọn sebi ọlọba. Wọn a náwó bí ẹni wí pé ilẹ̀ ọ̀la kò ní mọ́. Ọ̀pọ̀ tí ń ṣe bigimaanu ló... Read More
Adigunjale wọ Offa, wọn kówó, wọn tún fẹ̀mí ṣòfò Olayemi Oniroyin 4/06/2018 01:14:00 am 1 Comment Edit Àwọn adigunjale wọ ilu Offa lọjọ karùn-ún oṣù kẹrin ọdún yìí láti fọ banki. Àìmọye èmi lo ṣòfò, lára wọn ni ọlọ́pàá àti àwọn obìnrin. ... Read More
Ẹ wo bí wọn se pa àwọn ọmọdé nìpakúpa ni Taraba Olayemi Oniroyin 4/05/2018 01:01:00 pm Add Comment Edit Read More
Ohun tí àwon olopaa ṣe fún ìyá àgbàlagbà ni Abia ni yii Olayemi Oniroyin 4/05/2018 12:44:00 am Add Comment Edit Tí bá ń sọ nípa àwọn tí wọn wù ìwà ibajẹ, ó yẹ ká sọ nípa àwọn ọmọlúwàbí pẹ̀lú. Ní ìpínlè Abia, ìyá àgbàlagbà to ń bọ láti oko dá ẹyìn rẹ nù... Read More
Gómìnà ipínlẹ̀ Kano fi ori ru iyẹ̀pẹ̀ lónìí Olayemi Oniroyin 4/02/2018 08:33:00 pm Add Comment Edit Ẹnu yà ọ̀pọ̀lọpọ̀ lónìí nígbà tí gómìnà ipínlẹ̀ Kano, Abdullahi Ganduje, ṣe abewo si ise àkànṣe kan tí ń lọ lọ́wọ́. Gómìnà rí àwọn ènìyàn t... Read More
"Emir kìí se èdè Hausa", àlàyé Ọ̀jọ̀gbọ́n Farooq Kperogi tí ṣàlàyé ohun tó rújú Olayemi Oniroyin 4/02/2018 07:56:00 pm Add Comment Edit Ọ̀jọ̀gbọ́n Farooq Kperogi ọmọ Nàìjíríà tí ń sise olùkọ́ni ni ilu America tí ṣàlàyé wí pé, ìkà àbùkù nínà láàárín Yorùbá àti Haúsá láti ìgbà... Read More