Oyun Iju (Fibroid) |
Ọ̀kan nínú àwọn ololufẹ Olayẹmi Oniroyin ni wọn kọwe
ransẹ si wa lati ba wọn tọpinpin nípa iwosan fun oyun ìju ti awon oloyinbo n pe
ni “fibroid”.
Abajade
alaye mi si ni yii:
Oyun iju ki i jẹ ki oyun ọmọ gidi duro lara
obirin, orisirsi nnkan lo si le sokunfa iju (fibroid).
Sugbon gẹgẹ
bi abajade Olayemi Oniroyin lọwọ awon àgbàlagbà, ohunkohun yoowu to le sokunfa
ìju (Fibroid), iwosan rẹ naa ni ẹyìn ti ko ti i pọn (unripe palm kernel).
Unripe palm kernel and ripe palm karnel |
Lílò: Bi
obirin ba ni ìju (Fibroid), ki iru obirin bẹẹ gbiyanju lati maa jẹ ẹyìn ti ko
ti pọn (unripe palm kernel) bi ẹyọ ogún si mẹẹdogun (20- 25) lọjọ kan (in a
day) fun osu kan pere (a month).
Take (chew) 25
units of unripe palm kernels in a day for 30 days
Èpo ẹ̀yìn rẹ
lasan ni eniyan yoo jẹ. Asiko to si dara ju lati jẹ ẹ ni ti eniyan ba jẹun alẹ
tan ki ẹ to sun.
Unripe palm kernel |
Ni agbara
Olorun, ti iju (fibroid) naa ba ti dagba, obirin naa yoo bi iju naa bi ọmọ danu.
Ti ko ba ti dagba, yoo ya danu mọgbẹ ni. Alaafia yoo si deba iru obirin naa
lati lóyún ọmọ gidi.
Akiyesi pataki: Gege bi mo ti maa n so, emi ki i se
dokita, isẹ iroyin nise mi; iwadii ati itopinpin si ni bárakú fun mi. Olorun oba oluwosan, yoo se
iwosan fun gbogbo alailera pata. Amin.
Fun awon atejade mii nipa eto ilera, e wa SIBI
Thanks so much sir
ReplyDeleteYou are welcome
ReplyDelete