Bi eeyan ba we tan ti gbogbo ara ba n ja je; tabi ti ara ba n ja eniyan je ni gbogbo igba; tabi ki kokoro wa lara eni naa gege bi kuruna tabi eyikeyi kokoro ara.
Iwadii ijinle awon agbalagba Yoruba fi ye wa wi pe kokoro inu eje lo n faa awon nnkan wonyii.
Otito Oogun re ni eleyii:
A o wa egbo igi ti Yourba n pe ni Akogun, a o gun po ti yoo kunna daada. Leyin eyi ni a o da sinu igo tabi ike, a o da omi
osan wewe to po die sii.
Lilo Re: A o ma mu niwon sibi imuko laaro ati lale leyin ounje.
Eni ti o ba ni arun ogbe inu (Ulcer) ko
gbudo lo omi osan wewe, ki eni na lo omi lasan.
Orisun: HealthFirst
Atunko/Atunse: @OlayemiOniroyin
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
Ejo ara maan Jami je lekankan Kini mole se ejo
ReplyDeleteEjoo. Kini mo le looking fun ori yiyun ati nkan ti o ma un dabi elubo ni isale irun?
ReplyDeleteAra ma n jamije bi iseju mewa leyin ti mobawe tan pelu kankan sugbon see ole fa ki orikerike Ara komaa ro Yan?
ReplyDeleteAra mi ma se kulukulu kakiri kini mo le lo?
ReplyDeleteGbogbo ara lo maa n yun mi to si maa n se eje ti mo ba yun un tan,ki ni mo le lo si.
ReplyDeleteEjowo nkon ma nse kulukulu lago arami kini molelo si
ReplyDeleteEjo Baba, kini o mafa ki ese ma ta enia lati orukun si atelese
ReplyDeleteẸ jọ̀wọ́ kini mo lè lo fún ojú ara yiyun
ReplyDeleteKini o ma nfa Ori to ngba yii ti o si npariwo Ati Ara yiyun
ReplyDeleteEjo kini molelo,si ara ihunhun,,,ti o ba hun,mi oma le panpan
ReplyDeleteEjo se ewe akogun no oruko mi Tori awon eniyan ko mo
ReplyDeleteE jowo sir kini mo le lo si ara yiyun,ti yo si tun maa le
ReplyDeleteE se pupo
ReplyDeleteEwe Ati Egbo Ile Yoruba 1: Oogun Fun Gbogbo Kokoro Inu Eje - Iroyin Yoruba >>>>> Download Now
ReplyDelete>>>>> Download Full
Ewe Ati Egbo Ile Yoruba 1: Oogun Fun Gbogbo Kokoro Inu Eje - Iroyin Yoruba >>>>> Download LINK
>>>>> Download Now
Ewe Ati Egbo Ile Yoruba 1: Oogun Fun Gbogbo Kokoro Inu Eje - Iroyin Yoruba >>>>> Download Full
>>>>> Download LINK
Ewe Ati Egbo Ile Yoruba 1: Oogun Fun Gbogbo Kokoro Inu Eje - Iroyin Yoruba >>>>> Download Now
ReplyDelete>>>>> Download Full
Ewe Ati Egbo Ile Yoruba 1: Oogun Fun Gbogbo Kokoro Inu Eje - Iroyin Yoruba >>>>> Download LINK
>>>>> Download Now
Ewe Ati Egbo Ile Yoruba 1: Oogun Fun Gbogbo Kokoro Inu Eje - Iroyin Yoruba >>>>> Download Full
>>>>> Download LINK y1
Ekasan sir, e jo kini Eniyan le lo fun oyi ti o ma nmu ori fifo wa. Ori yen ma nfo mi ki oyi to wa.
ReplyDeleteThants very much
ReplyDeleteKini eniyan lelo tin nkan barinkiri ninu Ara
ReplyDeleteEkasa sir ki ni mo le lo ti oyun yio fi duro
ReplyDeleteE jowo sir kini mo le lo fun segede eke omode
ReplyDeleteEjo sir kini mole lo ti Ara ban Yun mi ati oju Ara ti mo ba we tan
ReplyDelete