Smiley face

Ewe ati Egbo Ile Yoruba 2: OOGUN IKO TI A TI LO OOGUN OYIBO SI TI KO GBO O

A o wa orogbo bi ogun si marundinlogbon (20-25),

Ataale ekun owo meta, ati
Aayu ekun owo meta bakan naa.

A o lo won kuna papo daadaa.

Leyin ti a ba ti se eyii tan, a o daa mo ogidi oyin igan kan.

Lilo: A o maa mu sibi imuko kan leemeta lojumo.


Orisun: HealthFirst
Atunko/Atunse @OlayemiOniroyin
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment