ÌGBÈYÌN láti owó RASBAM (5) Olayemi Oniroyin 3/30/2018 03:52:00 pm Add Comment Edit - 5 - Ojó n yí lu ojó, osù n yí lu osù, kèrèkèrè ó n pé odún keta lo tí Àjoké ti sá kúrò ní ìlú. Gbogbo nnkan le kòkò fún Àdìsá àti aya ... Read More
ÌGBÈYÌN láti owó RASBAM (4) Olayemi Oniroyin 3/27/2018 03:33:00 pm Add Comment Edit - 4 - Àdìsá gbá owó tìdùnnútìdùnnú, ó dà a sí àpò, ó sin Balógun sí ònà, bó se padà dé ó ké sí Àjoké àti ìyá rè láti fi tó won létí. Àdìsá... Read More
ÌGBÈYÌN láti owó RASBAM (3) Olayemi Oniroyin 3/23/2018 12:09:00 am Add Comment Edit - 3 - Sé wón ni bá a bá dá ogún odun pípé ní pé; béè bí a dá ogbòn osù ó n bò wá ku òla, èyí ló dífá fú... Read More