Àwọn onwoye nípa ọ̀rọ̀ òṣèlú tí ṣàlàyé wí pé, kò yẹ kó jẹ ohun ijoloju wí pé oga àgbá àwọn ọlọ́pàá ilẹ̀ yìí tún padà pe Bukola Sàràkí lórí ...
Read More
Home / Oro Oselu
Showing posts with label Oro Oselu. Show all posts
Showing posts with label Oro Oselu. Show all posts
Sàràkí lè dá Buhari lágbo nu
Inúfu-àyàfu ni ẹgbẹ́ òṣèlú APC wá báyìí pelu ahesọ ọ̀rọ̀ tí ń lọ kiri wí pé, Ààrẹ ilé igbimo asofin àgbà Abuja, Bukola Sàràkí kò ní pẹ fi ẹg...
Read More
Wọn tí yọ orúkọ Bukola Sàràkí kúrò nínú ẹsun idigunjale tó wáyé l'Ọffa
Àṣírí tí lu jáde báyìí wí pé wọn ti fà orúkọ Bukola Sàràkí kúrò nínú esun ìdaràn idigunjale tó wáyé nílùú Ọffa níbi tí àìmọye èmi ti ṣòfò. ...
Read More
Ilọrin Afonja tí tẹ́wọ́ gba Omoyele Sowore
Walahi sugar ja nílùú Ilọrin fa nígbà tí Omoyele Ṣòwòrẹ́ gbórí wọlé sílùú Afonja pẹ̀lú àwọn ikọ̀ #TakeItBack Ẹ wolẹ kẹ ẹ wẹnu ọkọ́ ...
Read More
Buhari tí de láti UK: Ohun tó ṣẹlẹ̀ sí Orunmila tí ṣẹlẹ̀ sí Buhari
Ààrẹ Muhammadu Buhari tí padà wálé láti ìlú Biritiko níbi tó ti lọ yọjú sì dókítà tí ń tọju rẹ. Ní alẹ ọjọ́ Jimoh, 11/05/18, ní bàálù aare b...
Read More
Àkúrẹ́ mi tìtì: Òkìkí Omoyele Sowore ń lọ sókè sí ní joojumọ
Ènìyàn tí kò dá nílé kò lè dá níta. Àìmọye àwọn ènìyàn lọ wà pàdé Omoyele Sowore, ẹni tí ń ṣe ọmọ ipínlẹ̀ Ondo, ni papakọ ofurufu ìlú Àkúré ...
Read More
Omoyele Sowore ṣe àbẹ̀wò sì Deji tiluu Àkúré
Oludije fún ipò aare lodun 2019, Ogbeni Omoyele Sowore ṣe àbẹ̀wò sì Deji tiluu Àkúré
Read More
"Ìyẹ́ ni wọn o má wo lẹ́yìn ẹyẹ, wọn ò lẹ́yẹ mu"- Dino Melaye ń fọ lẹ́yìn to bọ lọ́wọ́ kondo ọlọ́pàá laarọ yìí nílùú Abuja
"Ìyẹ́ ni wọn o má wo lẹ́yìn ẹyẹ, wọn ò lẹ́yẹ mu"- Dino Melaye ń fọ lẹ́yìn to bọ lọ́wọ́ kondo ọlọ́pàá laarọ yìí nílùú Abuja. Àárọ̀...
Read More
Àwọn ọlọ́pàá tí gbé Senator Ovie Omo Agege to kò àwọn ọmọ ìta wọlé igbimo asofin
Laarọ yìí ni àwọn ọmọ ìta yawọ ilé igbimo asofin àgbà Abuja tí wọn sì jí ọ̀pá àṣẹ sálọ. Ní báyìí àwọn ọlọ́pàá tí gbé Senator Ovie Omo Agege ...
Read More
Wọn tí fi bàálù gbé òkú Senator Mustapha Bukar padà sile
Senator Mustapha Bukar tí parí isẹ rẹ nílùú Abuja. Wọn tí fi bàálù gbé padà sí ìlú rẹ, Katsina. Kí Ọlọ́run Allah bá dárí gbogbo aise dééde ...
Read More
Kositọma dáadáa ní Buhari - Aláké tilẹ Ẹ̀gbá
"Kositọma dáadáa ní Buhari . Mo fọwọ́ síi kò padà wa nígbà kejì láti wá parí àwọn iṣẹ́ takuntakun tó ti bẹ̀rẹ̀ - Aláké tilẹ Ẹ̀gbá Oba A...
Read More
Ìdìbò kú oṣù mewaa, asofin méjì kú láàárín ọsẹ meji
Lẹ́yìn bí ọsẹ kan tí ọmọ ilẹ̀ igbimo aṣojú sofin n kan kù, Senator míì tún kù ní àárọ̀ òní ni ilu Abuja. Senator Mustapha Bukar to wá láti i...
Read More
Omoyele Sowore wọlé sí Naija pelu òkìkí nla
Àìmọye lọ tú jáde lónìí láti kí Omoyele Sowore , Olóòtú ìwé Ìròyìn Sahara Reporters , ẹni tó setan láti díje fún ipò ààrẹ kaabọ sì orileede ...
Read More
Orin òwe, orín ọtẹ, orín Sai Buhari tí gba gbogbo Bauchi báyìí
Ni ìpínlẹ̀ Bauchi wọn kó Buhari jẹ́ bí "abinci". Lọja Satide to kọjá yìí ni èrò bí èrò mecca tú jáde láti yọ ayọ̀ ọdún mẹta tí Sa...
Read More
Àwọn ọ̀dọ́ tú jáde nítorí Akinwunmi Ambode
Omi lẹgbẹ àwọn ọ̀dọ́ ni wó tú jáde láti ṣe iwode gege bí àpẹẹrẹ atileyin wọn fún gómìnà Akinwunmi Ambode láti jẹ gómìnà fún ìgbà kejì. Iwod...
Read More
Eewọ! Ṣe lotitọ ni Ààrẹ Buhari jẹbi eléyìí
Kini èrò tí yín?
Read More
Bukola Saraki tí ṣe tán láti díje fún ipò ààrẹ ọdún 2019
Ààrẹ ilẹ̀ ìgbìmọ̀ asofin àgbà Abuja, Bukola Sàràkí tí fi ìfẹ́ rẹ̀ hàn láti díje ipò aare orileede Nàìjíríà lọ́dún 2019. Gẹ́gẹ́ bí Olóòtú ìw...
Read More
Ikú dóró! Ọmọ ile ìgbìmọ̀ asofin Abuja míì tún ti papòdà báyìí
Umar Buba, ọmọ ilé igbimo aṣojú sofin Abuja, eleyii tó wà láti ipínlẹ̀ Kogi lọ tí filẹ bora báyìí. Umar Buba lọ salaisi lẹni ọdún mẹtadinlo...
Read More
Tinubu@66: Jagaban jùkò ọ̀rọ̀ sì PDP
"Àá tì sọ ohunkóhun PDP ni ka gbenudake. Òtítọ́ ni wí pé, fún ọdún mẹ́rìndínlógún ni PDP fi ja Nigeria lole, wọn kówó jẹ, wọn gbọnmu, w...
Read More
Subscribe to:
Posts
(
Atom
)