Smiley face

Ikú dóró! Ọmọ ile ìgbìmọ̀ asofin Abuja míì tún ti papòdà báyìí

Umar Buba, ọmọ ilé igbimo aṣojú sofin Abuja, eleyii tó wà láti ipínlẹ̀ Kogi lọ tí filẹ bora báyìí. Umar Buba lọ salaisi lẹni ọdún mẹtadinlogota lẹ́yìn àìsàn eléyìí to dá dubulẹ.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment