"Nnkan ọ̀fẹ́ tí baye àwọn ọ̀dọ́ Nàìjíríà jẹ. Wọn kò fẹ ohunkóhun ṣe, gbogbo ìgbà, sáà-ba-n-mu lorin tí wọn kọ. Bí sádákà, bí ìfà ni wọn...
Read More
Home / Iroyin Okeere
Showing posts with label Iroyin Okeere. Show all posts
Showing posts with label Iroyin Okeere. Show all posts
Àwọn dókítà tí dá ojú iriran padà fún ẹni tí wọn gùn lọ́bẹ lójú
Àwon dókítà ìlú South Africa ń ṣe bẹbẹ
Read More
Ọmọbìnrin to gbé ọyàn sì bàbà rẹ lẹ́nu: Ìṣẹ̀lẹ̀ to wáyé láàárín àwọn òyìnbó aláwọ̀ funfun
Arábìnrin Mercy Makinde lo ṣe àfihàn àwòrán yìí pẹ̀lú akole to wá nisale yìí lórí ayélujára. Ìṣẹ̀lẹ̀ ojú ayé gidi ni, kìí se arosọ rárá. Ì...
Read More
Sharpville Massacre: Ìṣẹ̀lẹ̀ burúkú to ṣẹlẹ̀ ni South Africa lọ́dún 1960
Ayajọ ojo oni, March 21, lodun 1960 ni àwọn òyìnbó ajẹ́lẹ̀ ṣekú pa àwọn ènìyàn dúdú ni orileede South Africa. Won ṣe àwọn ènìyàn dúdú saka...
Read More
Ọmọ Naija to jẹ Senator ní Italy tí bínú tán o
Ènìyàn dúdú àkọ́kọ́ ti yoo di Senator ní orileede Italy, Ogbeni Tony Iwobi, ti ṣe kilọkilọ fún àwọn ènìyàn tí wọn gba ọna ẹyin wọlé sí orile...
Read More
Aare Buhari níbi ayẹyẹ ayajọ òmìnira orile-ede Ghana
Aare Buhari ni ilu Ghana 🇬🇭 níbi ayẹyẹ ayajọ òmìnira ìlú náà.
Read More
Olówó ń sọrẹ olówó: Ọmọ Otedola pàdé Dangote
Ni orileede India, nibe ni Otedola, oyinbo elepo robi, tí gbé pade Alh Aliko Dangote. Ibe náà ni DJ Cuppy to jẹ ọmọ Otedola tí gbé yọmọ Dang...
Read More
"Ọkọ mi ń ṣe àgbèrè ni mo fi gé nǹkan ọmọkùnrin rẹ" - Ìyàwó
O ti tọ bí ọdún mẹ́wàá báyìí tí Sukhwant Kaur àti Azad Singh tí ń fẹ́ ara àwọn báyìí ni Joginder Nagar to wá ní arẹwà orile-ede India. Ṣùgb...
Read More
Diezani Alison-Madueke yọ wa rata ọbẹ̀ lọja
Àwọn ọmọ Adamọ tí ganni Diezani Alison- Madueke níbi to ti yọ wá rata loja nílùú London. Arábìnrin yìí ni minisita epo robi nígbà kan eléy...
Read More
OMO ỌDÚN MOKANLA (11YRS) TÍ LÓYÚN OṢÙ MÁRÙN-ÚN NÍLÙÚ CHINA (2)
Ṣáájú, a ti gbé ìròyìn ọmọbìnrin ẹni ọdún mokanla tí bàbá ẹni àádọ́ta (50) fún lóyún nílùú China. Àwọn òbí ọmọ náà tí ń gbìyànjú láti ṣe o...
Read More
Omo ọdún mokanla (11yrs) tí lóyún oṣù márùn-ún nílùú China
Ọmọbìnrin ọmọ ọdún mokanla, omo ile ìwé ìlú China lọ tí lóyún oṣù márùn-ún báyìí látàrí ibasun láti ọwọ ogbeni Liu Baoming (50yrs) to je aṣó...
Read More
Kosi iyato láàárín òkú àti bebi onike fún ibalopo
Ọkùnrin kan, Alex Brown, Oniroyin ilé Amerika lọ tí ṣe àpèjúwe ibalopo àwọn ọkùnrin pelu bebi onike fún ibalopo (sex doll) bí ìgbà tí ènìyàn...
Read More
Wọn tí dá ilé asewo bebi onike silẹ ni Jámánì
Láti bá àwọn bebi náà ni ajosepo, 40,000 ni wákàtí kan péré
Read More
Ọmọkùnrin tí ń jisu onisu wá tí ha sínú kòtò ọrun báyìí
Ọmọkùnrin tí ń jisu onisu wá lo tí ha sínú kòtò ọrun báyìí ni ìlú Mabel to wá lorile-ede Uganda. Ọmọkùnrin to fi ìyàwó ati awon omo sílè n...
Read More
Ọmọbìnrin ọdún mejo, wọn fi ipá ba sùn kí wọ́n to sọ òkú rẹ sórí akitan
Rògbòdìyàn tí bẹ silẹ báyìí ni orileede Pakistan eléyìí tó ti mú ènìyàn méjì ló. Rògbòdìyàn eléyìí tó bẹ̀rẹ̀ bi i fẹhonu hàn nípa bí àwọn a...
Read More
Eniyan merin lọ "sun" nínú ijamba oko ojú irin to waye ni orileede South Africa
Okere tán, àwon ènìyàn bí merin ni won tí sagbako ikú òjìji nínú ìjàmbá ọkọ̀ ojú irin to waye ni orileede South Africa. Gege bi a ṣe gbo...
Read More
Kayeefi! Won ti bere odun awon oku niluu Indonesia
Odun awon oku je odun kan pataki ti awon eya Torajan ti won wa ni Guusu Sulawesi ni orileede Indonesia maa n se. Odun yii je odun ka...
Read More
Owusu pada iku ojiji lojo odun ileya
Omokunrin kan lo ti koja lo sorun niluu Ghana nibi oun ati awon ore re ti n se faaji odun ileya to koja. Alaye oro ni yii lati owo Ci...
Read More
St Janet ati Ayantunde Oyinbo niluu Austria
#Collabo to gbona
Read More
Subscribe to:
Posts
(
Atom
)