Sebi ohun to ba joniloju, ni Yoruba n so wi pe o yanilenu. Awon onimo ijinle sayensi kan ni ilu China ti je ko ye wa wi pe iwadii tuntun ti fidi re mule wi pe alubosa (ko baa se pupa tabi funfun) le wo iba, efori abaadi, ati gbogbo kokoro ara pata, ko ba je kokoro inu ehin, inu eje, inu oju tabi eyi to wa ninu eti.
Koda, o n sise fun otutu ati awon aisan mii ti n ba eda ja ninu ara.
Lati lo alubosa fun iwosan ara, ohun ti e o se ni wi pe, e o la alubosa naa si meji tabi iye ti e ba le laasi.
E wa si oju alubosa naa de atelese yin ti e ba ti fe sun lale. Leyin eyi ni e o wo awotele-ese (sock) le ko le mu duro. Bayii ni yoo wa titi di aaro ojo keji.
Ki ile toomo, gbogbo kokoro ati aisan to wa laago ara pata ni alubosa naa yoo ti fa jade sita ti alaafia yoo si de ba ago ara yin.
E wa le pada se eyi niye igba to ba wu yin, ko si ewu nibe rara.
Babalawo soogun aiku fomode, o ni ko sise. E dakun, se omo naa ti ku na ni?
Awada lasan ni mo sebi nigba ti mo koko gbo abajade iwadii naa, sugbon nigba ti mo pada finmu finle daada, mo ri daju wi pe otito ni. Awon Yoruba sibo, won ni danwo lo bi iya okere.
Awon eniyan ti bere si ni dan orisii ogun yii wo ni awon ilu oke okun, gbogbo won naa lo si n jeri si i wi pe a-je-bi-idan ni ogun naa.
Orisii aisan wo lo n ba yin ja laago ara, se awoka ni tabi ara riro? Ko ba je kokoro ara tabi ako iba? Eyin e saa ti fi alubosa si atelese yin sun, o daju wi pe e o pada fi ope fun Olorun oba ni.
Alubosa ni agbara lati gbe kokoro tabi arun mi sinu, idi niyii ti won fi n gba wa nimoran lati yera fun jije aabo alubosa ti won ti ge to ti di ojo keji.
Olayemi Oniroyin, ibi ti maa ti duro ni yii. Sugbon maa royin ki e je ki awon ebi, ore ati ololufe yin ka akanse iroyin yii nitori wi pe o se pataki pupo gan-an ni. E se. Fun alaye siwaju, e tun le ka [NIBI]
O dabo!
Lati fi iroyin sowo si awon eniyan yii, e fi linki sowo si won: http://www.olayemioniroyin.com/2015/07/ise-iwadii-tuntun-e-wa-wo-ise-iyanu-ti.html
Adupe
ReplyDeleteIse Iwadii Tuntun: E Wa Wo Ise Iyanu Ti Alubosa N Se - Iroyin Yoruba >>>>> Download Now
Delete>>>>> Download Full
Ise Iwadii Tuntun: E Wa Wo Ise Iyanu Ti Alubosa N Se - Iroyin Yoruba >>>>> Download LINK
>>>>> Download Now
Ise Iwadii Tuntun: E Wa Wo Ise Iyanu Ti Alubosa N Se - Iroyin Yoruba >>>>> Download Full
>>>>> Download LINK d1
E seun o,olootu. E ku ise. A mo riri ise yin.
ReplyDeleteE seun o,olootu. E ku ise. A mo riri ise yin.
ReplyDeleteA dupe! Ajinde ara a ma je.
ReplyDeleteEseun gaani ajide ara a maje
ReplyDeleteIse Iwadii Tuntun: E Wa Wo Ise Iyanu Ti Alubosa N Se - Iroyin Yoruba >>>>> Download Now
ReplyDelete>>>>> Download Full
Ise Iwadii Tuntun: E Wa Wo Ise Iyanu Ti Alubosa N Se - Iroyin Yoruba >>>>> Download LINK
>>>>> Download Now
Ise Iwadii Tuntun: E Wa Wo Ise Iyanu Ti Alubosa N Se - Iroyin Yoruba >>>>> Download Full
>>>>> Download LINK