Okere tán, àwon ènìyàn bí merin ni won tí sagbako ikú òjìji nínú ìjàmbá ọkọ̀ ojú irin to waye ni orileede South Africa.
Gege bi a ṣe gbo, oko ojú irin náà lo kọlu oko ajagbe kan eleyii to kọ lati dúró nígbà tí ọkọ̀ ojú irin náà fe kọjá láti dabu ona ojú pópó.
Kete ti ìṣẹ̀lẹ̀ yìí sele ni ina seyo, títí gbogbo oro sì di fopomoyo.
Ilu Kroonstad to wa ni Free State ni isele yii ti gbe waye.
0 comments:
Post a Comment