Ká má parọ, ibùdókọ̀ yìí rẹwà gidi gan-an. Kosi ìyàtò láàárín rẹ atí àwọn ìlú tó ti gòkè àgbà lagbaye.
Ó kàn je wí pé karamọ àti ayẹyẹ tí wọn gbé lé e lórí ni kọ jẹ ka mọ bí a ti fẹ́ yín ijoba ipínlẹ̀ Èkó. Sibẹsibẹ Ambode fakọyọ!
O-se-ko-se, ṣe a lè fi Ambode we Ọ̀gbẹ́ni Kosẹlẹri tàbí maanu to má ń gé pọnmọ kiri ojú títì yẹn, àwọn gómìnà yahoo-yahoo 😂 🏃 🏃 🏃 🏃 mo rí yín na 🏃
0 comments:
Post a Comment