Eto Gbedemuke ose yii yoo tun lagbara pupo nigba ti maa ma gba Clemso, onkorin omo Nigeria, lalejo lati ilu Finland.
Omo Naija ni Clement Shola Ogundipe ti gbogbo eniyan mo si Clemso, sugbon ilu Finland lo ti n sise aje, o si wa lara awon omo Naija to wa loke okun ti n gbe Nigeria laruge.
Aago mesa-an aaro (9.00GMT) Sat [08:10:2016] leto, ma ti tete jide sinu studio tori traffic.
Ko si ilu te e wa ti e ko le ti gbo mi.
E pade mi lori itakun agbaye www.radiodiaspora.com.ng
E ku ikale
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment