Smiley face

PEGGY PADA JOBA!

Won ti ni ori ti o joba ko ni salai joba, orun ti o lo ejigba ileke ko ni salai joye atata, bee loro Peggy je eni ti apeja oruko re n je Peggielene Bartels.

Se bi ise akowe ni Peggy n se ni ilu Amerika ko to gba ipe ayo wi pe ko maa bo ni ilu baba re,ilu Aganyin(Ghana) wi pe oun ni Ifa mu gege bi oba tuntun.

Fun igba akoko, obirin de ade owo ni Ilu Tantum, fun igba igba akoko gbogbo eniyan se kaabiosi fun Oba Peggy tuntun to je.

Agbara kaka ko, kadara eda ko ni ye lailai.

Olayemi Oniroyin agbaye, adura mi ni wi pe koba tuntun gbo bi olugbongbotigbo, ki oba gbo bi awon agbakan-agbakan ti won gbo titi ti won fomoolu sonde sorun, omoolu yo titi, o si dokinni. Ase!

28EEEAE2
Sent from my BlackBerry wireless device from MTN
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment