Awon oko akero tuntun ti gomina Abiola Ajimobi fon kaakiri ilu eyi to n mu inu awon mekun dun latari iye ti won wo oko naa lowo tasere ni awon agbero kan tiri gege bi okuta fun ise ti won. Awon oko akero bogini to je wi pe ofe ni won gbe awon omo ile iwe ati awon osise ijoba ti won ba ni kaadi idanimo lowo, ti won si n gba Muri kan tabi Ogbon naira lowo awon ero yoko lai ni i se pelu ibi ti won lo se jina.
Nje Awa Le Gba Wi Pe Ajimobi Ba Oja Je Looto Bi?

0 comments:
Post a Comment