Oko ofurufu Dana Airline ti nomba re je 9J-357(LOS-ABV) la gbo wi pe o tun pada rababa wa sile ni kete ti won gbera soke ni nnkan bi ago marun-un lana ni papa oko ofurufu Murtala Muhhammed ni Ilu Eko.
Awako baalu naa eleyii ti o so fun awon ero wi pe ko si ewu bo ti n wule ko mo o, sugbon oun kan sakiye wi pe enjiini oko naa n wuko kan ti ko ye oun ni. Oun ko si fe fina sori orule sun ni oun tun fi jo ijo oun wa le, ti oun si ko o mole daada nitori emi o laaro.
Ti e ko ba si gbagbe laipe yii lo pe odun kan geerege ti oko Dana kan fi emi aimoye awon eniyan sofo.
Olayemi Olatilewa
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment