Smiley face

Awon Soja Pa Ogota Boko Haram

Awada kan mbe ti won maa se wi pe ti Soja ba gba o leti, o mo lotito wi pe Olopa lore re" Awon omo Boko Haram bi ogota la gbo wi pe awon omo ologun ile yii ti ran lo sorun apapandodo bayii ni ilu Maiduguri ti alaafia si ti n pada wo inu ilu naa diedie.
Olayemi Olatilewa
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment