Gomina ti Ipinle Edo, Gomina Adams Oshiomole ti fi ofin de okada ni popona tibu-toro olu ilu Ipinle naa ti o je Benin.
Gomina so ni ojo Isegun ana yii(11/6/13) wi pe pupo ninu awon isele ka maa jini gbe salo lo je wi pe okada ni won fi n se ise buruku naa.
Ni bayii, o ti di ese nla lati ri okada ni awon ijoba ibile Ikpoba Okha, Oredo and Egor ti won gbe ilu Benin ro.
Olayemi Olatilewa
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment