Smiley face

Ile Adebisi Ni Idi-Ikan

Igba ni nnkan laye. Asiko si ni gbogbo nnkan pelu. Awon Yoruba bo won igba ko lo bi orere, sebi igba kan lo ni, igba kan si bo naa ni.


Ile Adebisi Ni Idi-Ikan, Ibadan

Olayemi, mo pinnu lati se afihan ile Adebisi ni Idi-Ikan ni ilu Ibadan feyin ololufe OLAYEMI ONIROYIN latari ero mi nipa ohun aye yii ti ko lo titi.

Ile Adebi je ile olokiki ni ilu Ibadan laye atijo eleyii ti ko si elegbe re lailai. Ni aye igba naa, won tile maa n dasa wi pe "N kole mi bi Ile Adebisi afai ni i ko nnkankan nu-un"

Ile Adebisi ti n wu gbogbo eniyan laye ojo si lo ti dohun ti ko si eni ti n gbe inu re mo bayii.
ko si ohun ti ko ni tan, ko si ohun ti igba koni lo lori re. Bintin laye yii, e je se pelepele.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment