Jose Mourinho ti so wi John Terry naa ni o maa je asaaju egbe agbaboolu Chelsea fun igba keji ti o oun tun tewo gba isakoso egbe agbaaboolu naa.
![]() |
| Ipadabo Mourinho |
John Terry, eni ti o ti fi awon igba kan faseyin gege bi asaaju lawon igba ti oga re Mourinho fi dagbere fun egbe agbaboolu Chelsea.
Mourinho so wi pe o je idunnu oun ati awon ololufe egbe agbaboolu naa lati ri John Terry gege bi asaaju ti a mo si captain.

0 comments:
Post a Comment