Smiley face

Kelly-Hansome Korin Fun OJB

Kelly Hansome ti gbe orin jade lati fi pe akiyesi awon eniyan fun iranlowo owo fun Babatunde Okungbowa eni ti gbogbo eniyan mo si OJB latari aisan kidinrin to n yo lenu eleyii ti won fe lo se itoju re ni ilu India.


Akole orin naa to pe ni "SaveOJB" lo so wi pe oun ko gbe orin naa jade latari ife tara ohun lasan bikose nipa ore ati imole oun to wa lori idubule aisan.
Olayemi Olatilewa
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment