Smiley face

Awon Omo Mi Lo Fomije-Keshi

Leyin ti ile Naijeria ti fidiremi ninu idije FIFA Confederation Cup ti n lo lowo ni ilu Brazil, olori adari boolu Naijeria Stephen Keshi so wi pe pupo ninu awon omo ti ohun ko lo je wi pe won ko se bi oun ti se lero to eyi gan-an lo si fa ifaseyin to waye ninu idije naa.
Olayemi Olatilewa
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment