Ni bayii, won ti fi onte lu Carlo Ancelotti gege bi olukoni egbe agbaboolu Real Madrid. Ninu atejade to fonkiri ero ayelukara lojo isegun ose yii (25/6/13) ni won ti so wi pe odindin odun meta gbako ni Ancelotti yoo fi maa wa oko egbe agba boolu naa bi eni n wa baalu.
Olayemi Olatilewa
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment