Smiley face

Kobura Ajisafe Yinbon Mo Omo Ile Iwe

Ti won ba n se adura wi pe eni ti e ti baje ko ni ba ti wa je , o ye ki eniyan se amin nla ko tun gbe ito ami mi ni. Olopa kan ti oruko re nje Ajisafe Amos la gbo wi pe o sadeede gbe ibon soke to si yin kusaaa si oko(car) omo ile iwe ifafiti ijoba apapo to wa ni Ibadan kan lenu iloro ile iwe naa.
Kaadi Idanimo Olopa To Yinbon

Olori egbe akekoo ile iwe naa ti fariga bayii wi pe idajo ododo ni lati waye lori oro naa, o si so wi pe awon ti ri kaadi idanimo olopa naa gba ati awon eri to se koko tori o n de iwaju tan ki won maa dori oro kodo wi pe eni yinbon ki i se olopa mo.

Moto Adewale Adegboyega ti o je omo ile iwe U.I ti won yinbon mo

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment